Kí ló dé tí ọrọ̀ ajé Áfíríkà ń dàgbà sókè, àmọ́ tíìgbé ayé adúláwọ̀ ń rẹ̀yìn?

Àkọlé fídíò, Ọrọ̀ ajé Áfíríkà ń dàgbà sókè, ìgbé ayé ọ̀pọ̀ ọmọ adúláwọ̀ ń rẹ̀yìn
Kí ló dé tí ọrọ̀ ajé Áfíríkà ń dàgbà sókè, àmọ́ tíìgbé ayé adúláwọ̀ ń rẹ̀yìn?
Published

Ilẹ Afirika jẹ ọkan ara ẹkun kan lagbaye to n rí dagbasoke ọrọ aje agbaye ni ọdun yii, sugbọn se eyi mu ki aye dẹrun fawọn ọmọ ilẹ Afirika bi?

Ki lo wa de tawọn orilẹede Afirika n lọ soke nidii ọrọ aje amọ ti awọn eeyan adulawọ n yi ninu isẹ ati osi to lagbara?

Ninu fidio yii, ẹ wa wo atupalẹ ohun to fa isẹlẹ naa atawọn igbesẹ to yẹ kawọn adari orilẹede lawọn ilẹ adulawọ gbe lati mu ki agbega ọrọ aje wọn nipa lara awọn eeyan wọn