"Àádọ́ta mílíọ̀nù ni wọ́n ní ká san fún ìtúsílẹ̀ wa"

Àkọlé fídíò, "Àádọ́ta mílíọ̀nù ni wọ́n ní ká san fún ìtúsílẹ̀ wa"
"Àádọ́ta mílíọ̀nù ni wọ́n ní ká san fún ìtúsílẹ̀ wa"
Published

BBC ṣèwádìí lórí bí àwọn ajínigbé ṣe ń jí àwọn àgùnbánirọ̀ gbé tí ọ̀gá àgbà NYSC sì sọ àwọn ìgbésẹ̀ tí wọ́n ti ń gbé láti kojú ìṣòro náà.

Ẹ wa gbọ alaye ọmọbinrin kan nipa bo se bọ sọwọ awọn ajinigbe lasiko to n lọ sinru ilu ati bi o se bọ lọwọ wọn.