Olaniyan 'Idamu Industry' Oluwatosin jẹ́wọ́ pé ẹnu nìkan kọ́ lòun ní lórí ètò 'Ṣé o láyà?'

Olaniyan 'Idamu Industry' Oluwatosin jẹ́wọ́ pé ẹnu nìkan kọ́ lòun ní lórí ètò 'Ṣé o láyà?'
Published

Ilumọọka adẹrinpoṣonu ni Olaniyan Oluwatosin ti ọpọ eeyan mọ si Idamu Industry.

Amọ ṣa, lori eto Se o laya tọsẹ yii, o da bẹbẹ pẹlu awọn ibeere wa gbogbo.

Ibeere loriṣiriṣi ni o dojukọ lori eto tọtẹ yii, bo tilẹ jẹ wi pe ẹnu yii naa ko jẹ ki Idamu Industry gbadun, sibẹ, o jẹwọ ara rẹ pe ẹnu nikan kọ loun ni o, oun mọ nipa aṣa ati iṣe Yoruba daadaa.

Ẹ wa nnkan fidi le lati gbadun awọn idahun Idamu Industry lori ibeere ti BBC Yoruba bi i lori eto wa, Ṣó o Láyà.