Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ọdun mẹrin ko ni to fun lati pari gbogbo iṣẹ takuntakun ti mo bẹrẹ, mo nilo ọdun mẹrin mii
Gomina ipinlẹ Osun, Ademola Adeleke lo sọ bẹẹ fun BBC
Adeleke ni ọpọ lo n bu ẹnu atẹ lu oun pe oun ko mọ ju ijo lọ
Amọ ogunlọgọ ọmọ ipinlẹ Osun lo n jẹri awọn iṣẹ idagbasoke ti oun ti ṣe bayii
Lọ soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
_____________________________________________________________________
Arabinrin Rachael Alamu to ṣẹṣẹ gba itusilẹ lakata agbesunmọmi pẹlu awọn akẹkọọ rẹ nipinlẹ Oyo, ti sọ pe
Awọn agbesunmọmi naa fiya jẹ awọn ọmọde to wa ninu wọn lasiko ti wọn wa lakata wọn ninu igbo
O ni wọn na awọn ọmọde ọhun, koda wọn n fi aṣọ bo ẹnu wọn ki wọn ma baa ke
______________________________________________________________________
Ẹwẹ, gomina Seyi Makinde ti darukọ eeyan marun to ku lasiko to wọn n gbiyanju lati doola awọn akẹkọọ ati olukọ naa
Lara wọn ni ẹṣọ eleto aabo, awọn ọlọdẹ atawọn ẹṣọ Amotekun nipinlẹ
To ba fẹ mọ orukọ awọn to ba iṣẹlẹ naa lọ


