You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ẹgbẹ́ òṣèlú ADC ti fọwọ́ òsì júwe ilé
Fún alága tẹ́lẹ̀ rí nínú ẹgbẹ́ náà àtàwọn mẹ́sàn-án míì níbi ìpàdé àpérò ẹgbẹ́ tó wáyé lọ́jọ́ Ìṣẹ́gun
Níbi ìpàdé náà ni wọ́n tún ti ṣàtúnṣe sí ìwé òfin ẹgbẹ́
Tí ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní Nàìjíríà sì sún ìgbẹ́jọ́ lórí àwọn adarí ẹgbẹ́ sí ọjọ́ Kejìlélógún
Kí wá ni ipa àìsí aṣojú INEC níbi ìpàdé le ní lórí ẹgbẹ́
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn wà lójú òpó wa
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Dárúkọ, pẹ̀lú ẹ̀rí tó dájú, àwọn tó fi rìbá lọ̀ ọ́ láti gbé ìgbésẹ̀ ìyọnípọ̀ Makinde
Olórí àná ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Oyo, Adeolu Adeleke ló sọ bẹ́ẹ̀ fún olórí aṣòfin, Debo Ogundoyin
Adeleke ní tí Ogundoyin kò bá ṣàlàyé ọ̀rọ̀ náà ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ó ṣeéṣe kó jẹ́ àkóbá fún-un lọ́jọ́ iwájú
Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn náà ní BBC News Yorùbá
xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx
Póòpù ìjọ Aguda, Pope Leo XIV ti balẹ̀ sí orílẹ̀ èdè Cameroon
Lára àbẹ̀wò ọlọ́jọ́ mẹ́wàá tó ń ṣe sílẹ̀ Africa
Àwọn èèyàn Cameroon ní ìgbàgbọ́ wà pé
Ó ṣeéṣe kí àbẹ̀wò póòpù yìí fòpin láàsìgbò tó ń wáyé ní ẹkùn tí wọ́n ti ń sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì ní orílẹ̀ èdè náà