Ìpinnu mi láti di gómìnà ìpínlẹ̀ Osun jẹ́ kádàrá èmi àti Ọlọ́run – Bola Oyebamiji olùdíje APC

Àkọlé fídíò, Ìpinnu mi láti di gómìnà ìpínlẹ̀ Osun jẹ́ kádàrá èmi àti Ọlọ́run – Bola Oyebamiji olùdíje APC
Ìpinnu mi láti di gómìnà ìpínlẹ̀ Osun jẹ́ kádàrá èmi àti Ọlọ́run – Bola Oyebamiji olùdíje APC
Published

Bọla Oyebamiji ti ọpọ mọ si AMBO ṣalaye pe oun ko nii lọkan ni ibẹrẹ pẹpẹ ṣugbọn nnkan lo di nnkan ti oun fi gbera sọ lati gbe igba oṣelu

O ṣalaye siwaju sii pe iṣẹ agbẹ loun yoo mojuto nitori pe iṣẹ agbẹ jẹ iṣẹ ti mutumuwa ni ipinlẹ Ọṣun mu lọkunkundun.

Ẹ wo fidio yii lati mọ sii awọn ọrọ ti AMBO sọ.