Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Skip Móríwú and continue reading

Móríwú

  • Dokita kan n ye Ọlẹ̀ meji wo ninu alaboyun
  • Aworan Emmanuel Modurotimi Olubodede to wọ asọ kootu alawọ paali ti o joko to si n sọrọ
  • Bimpe Akintunde wọ asọ aran alawọ eweko, o si we gele rẹ
  • Theophilus Adegbohungbe to n fi ede Yoruba kọ awọn eeyan ni Tech wọ asọ sokoto ati ẹwu olomi aro ati fila alawọ goolu
  • Aworan ọkunrin kan to n sun lori bẹẹdi lapa oke ati aworan atọkun eto to n sọrọ lapa isalẹ
  • Aworan oloogbe Aderogba
  • Taiwo Okikiola (Omo elejo tawọn eeyan tun maa n pe ni Ifa lejo). O gbe ejo ejo kan k'ọrun.
  • Obinrin to n sun lori ibusun pẹlu awọtẹlẹ funfun to fi ara silẹ ati olootu to n salaye ọrọ
  • Eyiyemi Afolayan wọ asọ oloyinbo kootu alawọ pinki, o si fi irun atọwọda sori
  • Patience Adekunle wọ sokoto penpe ati asọ T-Shirt, o tẹri mọlẹ n to waya to fẹ fi ya aworan
  • Gomina Abiodun Oyebamiji wọ agbada toke tilẹ alawọ eeru, o mu iwe idibo lọwọ lati dibo ni agọ idibo rẹ.
  • Obinrin alawọ funfun ati alawọ dudu
  • Ọkan lara awọn eeyan Ago Ireti niluu Akure

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ